AKE NI IGBA EWE BY WOLE SOYINKA
Itan iriri oloikiki onkowe nni, Wole Soyinka nigba ti o wa ni omode ni agbo ile alufaa ni Ake, ninu ilu iwe ati ni igboro Abeokuta ni o wa ninu iwe yii. Eko pataki ni a ri ko nipa ipo omode lawujo Yoruba ati nipa oju to omode fi n wo aye. Awon iranti anfaani nipa itan Abeokuta nigba ogun agbaaye keji ati nipa ajagbara awon obinrin Egba lo so iwe yii di koseemaka fun gbogbo omo yoruba.